Gospel Music Nigerian Gospel Songs Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise

Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise

Download Loro Lero Ati Nise MP3 by Tope Alabi

The renownedย Nigerian praise worshipย gospel singer and songstress who has won lots of great award in the Christian music industry โ€œTope Alabiโ€ comes through with aย powerfulย tune, as it always comes in the Yoruba dialect. This song is titled โ€œLoro Lero Ati Niseโ€œ from her 2020 released HYMNAL album.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed always.

DOWNLOAD HERE

Lyrics: Loro Lero Ati Nise by Tope Alabi

Verse 1
Emi ofe o oluwa, agbara aโ€™tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

Chrous:
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

Verse 2
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owoโ€™tun re
Iranwo re yo mumi dโ€™ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

Verse 3
Emi o mayo sโ€™oluwa, oba ati ase mi
Fiโ€™bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola atโ€™ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise

Comment below with your feedback and thoughts on this post.