Gospel Music Nigerian Gospel Songs Tope Alabi – Kabi O Osi (Mp3 + Lyrics)

Tope Alabi – Kabi O Osi (Mp3 + Lyrics)

Download Kabi O Osi MP3 by

The prolific Nigerian praise worship gospel singer and songstress who has won lots of great award in the Christian music industry “Tope Alabi” comes through with a powerful tune, as it always comes in the Yoruba dialect. This song is titled “Kabi O Osi“.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed always…

DOWNLOAD MP3 HERE

Video: Kabi O Osi by

Kabi O Osi Lyrics by

Kabi o osi
Kabi o osi
Arugbo ojo, ad'agba ma tepa
Kabi o osi

We worship You, Kabi o osi
We worship You, Kabi o osi
Arugbo ojo, ad'agba ma tepa
Kabi o osi

Won o mu o lo l'edi ki won fi ewe akoko le o lori n'be
Ko s'awon to gbinmo po lati so pe eje a fi joba
Ab'awon wo lo duro, tan ni won a majoba n'idile won gan
Awon wo lo fi o je t'o ffn j'oba kon da wa l'ohun
Ta leni isaju to mu o wa s'inu orun
Ta leni to fa o ni tete wonu aye pe ko wa daye
Oya, k'eniKan fi baba tabi iya re han wa o, aare

Kabi o osi
Arugbo ojo ad'agba ma tepa l'oruko re
Kabi o osi

O l'oyun ara re, obi'ra e, o s'ora e loko
Ipa ti o se bi l'eere, eni ti o se yi pada
Ite re l'orun kii si, onipo ta o le ro l'oye
Arugbo ojo ni o, ad'agba ma tepa o
Eh.. iwo ni Ka bi o osi

Riru omi okun po, nje won o ni dake to ba l'oto
Iyanrin nla tun wa, to ba k'aye tan se won o ni pare
Igba t'ohun gbogbo ta ko ba di wiwo pale iwo ni o ku o
Arugbo ojo, onilu a lu la'torun o
Eh eh eh eh eh Kabi o osi

O ko d'aye eru b'aye pe kilo fe wa ninu ohun
Igba to da aye tan, o m'ohungbogbo s'aye e kon maj'oko won
O ti n gbe'biKan ki o to ko orun aare nla ni o, o se tu
Ailetuwo Adahunro Adahunso OlunKankun ni o
Arugbo ojo, ad'agba ma tepa ooo
lwo ni Ka bi o osi

Omomo to mo'yun sinu alaboyun to fori feti fenu si
O fimu o f'ohungbogbo Sibe e, o de d'igba Kan o bi
Se bi bo ba pe ki mimi o ma mi, tani njebe o
lwo ni Kabi o osi

Agbara re po o ju tara lo, iwo lo da ara
Okun re po ko de le pin, oni'mi iye
lwo lo mimi'ye si amo lasan to pada wa d'eniyan
Eh eh eh eh Kabi o osi

Oba ti'n fobaje, Oba to le r'oba Iloye to le ni ko ma mi mo
Oba ta o gbodo bi bo ba se'n sise owo re si
Ojo n'ro oye n'fun be l'orun ran l'asiko re o

Agbara re po o
Kabi o osi

Mo ni Kabi o osi
Kabi o osi
Kabi o osi
Alagbada ina, Alawotele oorun
Eh eh eh Kabi o osi

Comment below with your feedback and thoughts on this post.