Gospel Music Nigerian Gospel Songs Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise

Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise

Download Loro Lero Ati Nise MP3 by Tope Alabi

The renowned Nigerian praise worship gospel singer and songstress who has won lots of great award in the Christian music industry “Tope Alabi” comes through with a powerful tune, as it always comes in the Yoruba dialect. This song is titled “Loro Lero Ati Nise“ from her 2020 released HYMNAL album.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed always.

DOWNLOAD HERE

Lyrics: Loro Lero Ati Nise by Tope Alabi

Verse 1
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

Chrous:
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

Verse 2
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

Verse 3
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise

Share Your Thoughts below