Gospel Music Nigerian Gospel Songs Sola Allyson – Mo Juba (Mp3 + Lyrics)

Sola Allyson – Mo Juba (Mp3 + Lyrics)

Download Mo Juba MP3 by

Here an amazing song from the Nigerian soul, folk and gospel singer, and song-writer, who came into limelight with the hit album Eji Owuro. Sola Allyson-Obaniyi who is popularly known as Shola Allyson comes through with this song titled “Mo Juba“.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed always…

DOWNLOAD MP3 HERE

Mo Juba Lyrics by

Mo juba Oba
Iba Eledumare, to ni gbogbo ogo
Atererekariaye Olorun Awon Omo Ogun
Mo juba Oba
Iba Eledumare, to ni gbogbo ogo
Atererekariaye Olorun Awon Omo Ogun
Mo juba Oba
Iba Eledumare, Oba to ni gbogbo aye
Eni nla ti mbe lori ite titi lai lai lai
Emi mi b'ola fun O o lati ogbun iseda mi
Mo yi ka otun, mo yi t'osi mo ba ruburubu
F'Eni naa Alaponlejulo, Eni Ayeraye
Iwo lo ti mbe, Iwo loo si ma be,
Leyin Re, ko si mo, Oba titi lai
Mo sin O
Lat'ogbun emi mi
Eni naa, Oba naa, Oluwosan, Alaanu
Gbogbo iseda ati emi, a n b'ola fun O
Mo juba Oba
Iba Eledumare, to ni gbogbo ogo
Atererekariaye Olorun Awon Omo Ogun
Mo juba Oba
Iwo ni Oba ti o le pa'poda lailai
Oba to ti wa ti o si ma be tititi
Aye mi yio ma fi ibukun fun oruko Re
Ileke ola, Ipile oye, opin gbogbo ola
Gbogbo ise Re ni o ma yin O, a n pe O lOba
Iwo ni Alaanu to f'ebun se mi loso
O tun fi ogo de ebun to fun mi lade
Odo Re naa ni gbogbo ogo naa n pada si Oluwa
Eni naa, Oba naa, Oluwosan,
Alaanu Gbogbo iseda ati emi, a n b'ola fun O
Gbogbo ise Re ati emi o
A n b'ola fun O
Awon ohun taa ri at'awon ta o ri, won n b'ola fun O
A n b'ola fun O
Loke orun lohun, lagbedemeji ile t'a n te, ogo ni f'ooko Re
A n b'ola fun O
Iwo ni O ni ike to po, Olola to po, Alaanu to po
A n b'ola fun O
Ko si ede naa ni gbogbo aye ti iro ogo Re kii buyo Oluwa
A n b'ola fun O
Hiho okun n bu ola fun O, Osa naa n b'ola fun O, gbogbo ise.
A n b'ola fun O
Gbogbo ede, gbogbo ijoba, lo n wariri fun Oruko Re
A n b'ola fun O
Gbogbo ise Re ati emi
A n b'ola fun OTranslate to English

Comment below with your feedback and thoughts on this post.