Gospel Music Nigerian Gospel Songs Sola Allyson – Ayanmo Ife (Mp3 + Lyrics)

Sola Allyson – Ayanmo Ife (Mp3 + Lyrics)

Download Ayanmo Ife MP3 by

Here an amazing song from the Nigerian soul, folk and gospel singer, and song-writer, who came into limelight with the hit album Eji Owuro. Sola Allyson-Obaniyi who is popularly known as Shola Allyson comes through with this song titled “Ayanmo Ife“.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed always…

DOWNLOAD MP3 HERE

Ayanmo Ife Lyrics by

Hmmm isinmi
Okan mi mo isinmi
Okan mi mo isinmi
Modupe okan mi mo isinmi
Modupe okan mi mo isinmi
Mo yo nini igbaya pelu ore ofe eni to da mi
Modupe okan mi mo isinmi
Emi re ta fefe aye gba kiri nigba kan ri
Emi na ma ni ti mi o mo isinmi rararara lokan mi
Mo gba imole baba lati to mi sona isinmi
Okan mi n mi ele si'pa odo isinmi
O f'aanu gba mi O to mi sona isinmi
O pe mi wole O pe isinmi sokan mi
O pe mi wole O pe isinmi sokan mi
Okan mi mo isinmi
Okan mi ti mo isinmi
Mo dupe okan mi okan mi mo isinmi
Mo ma dupe okan mi ti mo isinmi
Mo yo ninu laasigbo pelu ore-ofe eni to da mi
Mo dupe okan mi ti mo isinmi
Emi re ti wahala aye n gba kiri nigba kan ri
Emi na ma ni ti mi Ololufe wo oju mi
So fun mi p'oo fe mi
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
Ololufe wo oju mi
So fun mi p'oo fe mi
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O wa fi idanu si'nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
O fi idanu si'nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
Ayo wa ti d'ajose
Ola wa ti d'ajoni
Irin wa ti d'ajorin
Ibanuje ko jina si wa
Wo mi o tun mi wo pel'oju inu
Irin wa laye jo'ra won
Wo mi o tun mi wo pel'oju inu
Irin wa laye jo'ra won
Ayanmo wa j'ayanmo
Loro ife wa se se regi
Ayanmo wa jo ayanmo
Loro ife wa se se regi
Owo mi ree o fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
Ko le se ki ija ma wa
Jowo je a jo s'asoye
B'oro ba se bi oro
Jowo fi suuru ba mi se
Ore okan mi pe mi o bi mi
Ogiri wa ko ma a la'nu
Ore okan mi pe mi o bi mi
Ogiri wa ko ma a la'nu
B'aa ba f'imo wa s'okan
Oke oke la o ma lo
B'aa ba f'imo wa s'okan
Oke oke la o ma lo
Owo mi ree yi o fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
Ololufe wo oju mi
So fun mi p'oo fe mi
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
Ololufe wo oju mi
So fun mi p'oo fe mi
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O wa fi idanu si'nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
O fi idanu si'nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
B'afefe idanwo ba fe de
Duro ti mi o girigiri
B'o ti wu k'oorun mu to
Sanmo dudu a wa dandan ni
B'afefe idanwo ba fe de
Duro ti mi o girigiri
B'o ti wu k'oorun mu to
Sanmo dudu a wa dandan ni
Iwenumo ma lo je, ka tun le r'aanu gba si ni
Isoro oni adun ola ni, ayo at'ope lo ma ja si
Owo mi ree yi o fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O wa fi idanu si'nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
O fi idanu si'nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O wa fi idanu si'nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
O fi idanu si'nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O wa fi idanu si'nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
O fi idanu si'nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat'odo Eni to da wa
o mo isinmi perepere lokan mi
Mo gba imole Jesu lati to mi sona isinmi
Okan mi n mi ele ele si'ba odo isinmi
O f'aanu gba mi O to mi sona isinmi
O pe mi wole O pe isinmi s' okan mi
He called me to His kingdom and gave my soul rest
O fi idande funmi, O fi igbala fun mi
O tan imole fun mi
O tun fi imisi si fun mi
Okan mi ti mo isinmi
Okan mi ti mo isinmi
Iwo na wole aye sii nbe fun o wole ko wa gba isinmi
All ye that labour and are heavy laden e waa gba isinmi
Yo fi idande fun o, ninu gbogbo ide aye a tu o
Yo tan imole fun o, wa gbagbe osi re bi omi to n san lo
Okan re a moo isinmi
Okan mi mo isinmi
Okan mi, okan mi ti mo isinmi
Mo dupe okan mi ti mo isinmi

Comment below with your feedback and thoughts on this post.