Download Imole MP3 by Sola Allyson
Lyrics: Imole by Sola Allyson
Jesu
Imole
Ategun ati afara sibi imole
Jesu
EnitโO wa
Ife e Baba
Sโeni tโo fe dโomo
You May Like These Too ๐ฅ
Repeat
Imole, latโinu imole
O wa lati da wa pada sโona imole
Ooun tโo gbโaye
Ko je kโon mo imole
Won diโte moo ife e baba
Olorun ninu eniyan
Eniyan ninu Olorun
Ilekun awon aguntan sinu ile aanu
Ipase eniti mo gba igbala
Nโaye tii fi funni ko
Imole sโookun aye e mi
Olusewosan emi i mi
Jesu
Imole
Ategun ati afara sibi imole
Jesu
EnitโO wa
Ife e Baba
Sโeni tโo fe dโomo
Eni nwa imole
Won ri ii imole
Won o mo mole
Won diโte imole
Irora yen po gan
Eje atโomi nsan gan
Sibe o n sโagbawi fun wa
Pe baba dariji won
Won o moโohun a nse
Baba dariji wa o nitori imole
Ninu irora re o tun fi iyonu mu ole re para
O ni iya wo omo re, omo wo iya re
O kigbe lโohun rara
Olorun mieese tโo o ko mii le
Eese tโo o ju mii le
Eese tโo o yin mi nu
Ongbe po gan, oti kikan lโaye fun un
Awon tโo nwa imole o, won fโiya je imole
O ba pari, o pari
Imole fโemi e sโowo o baba
O pari!
Nitori imole, nitori imole
Aso ipele ya o
Nitori imole
A le pe baba ni baba nitori imole
Isa oku dโofo
Eni ba fe le wa dโomo
Jesu, oga ogo, olori ogun orun
Omo alade alaafia
Alase orun, aye e baba
Baba lโaaye o, Baba lโaye
Aye e mi tire ni
Tn imole nipase mi
Ogo o mi kโo fogo fun o
Ola a mi kโo bu ola fun o
๐ต Are you a gospel artist? Get your song featured on CeeNaijaReach millions of gospel music lovers
PromoteJesu, iwo ni imole
Ategun ati afara sibi imole
Jesu enitโowa
Mo juโba re, enitโoso mi dโomo
๐ All songs and media on this page are shared for gospel promotion purposes only. All rights belong to the respective artists and labels. If you are the rights holder and wish content removed, please read our DMCA & Copyright Policy or submit a takedown request here.

