Gospel Music Nigerian Gospel Songs Sola Allyson – Adura Ololufe (Mp3 + Lyrics)

Sola Allyson – Adura Ololufe (Mp3 + Lyrics)

Download Adura Ololufe MP3 by

Here an amazing song from the Nigerian soul, folk and gospel singer, and song-writer, who came into limelight with the hit album Eji Owuro. Sola Allyson-Obaniyi who is popularly known as Shola Allyson comes through with this song titled “Adura Ololufe“.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed always…

DOWNLOAD MP3 HERE

Adura Ololufe Lyrics by

Adura mogba fun e ololufe mi
Ire ni mo n su fun e ayanfe oko mi ore mi
Oo ni kagbako l'aye oo ni r'ogun akoba
Oo ni s'irin l'aye be oo ni t'oju ile mole
Ainif'okanbale o ni y'odo re lailailailailai
Oo ni m'osi l'aye, aye re a ma dara si
Ife eledumare ree e ooo ore mi
O fewa fun re, o fewa f'ayo taa ba barawa s'otito
Angeli alayo mi faramo tire nse ni won njo s'ise
Iranse alaanu re wa pelu t'emi nwon njo rin po ni
Ibaase ‘wo layo pupo latagbala eledumare wa inu oluwa aa dun si
Ibaase' wo layo pupo latagbala
Eledumare wa o, inu oluwa aa dun si wa
Oba ni a lowo a bi'mo
Oba ni a s'owo a j'ere
Oba ni a r'aje jeun
Imole aa ma tan si
Imoran mi ree fun e ooo oloro mi
Imoran ni mo n gba e ninu ife to jin oloro mi maa gbo
Pe ko maa s'ora se, ore mi at'orun s'ora se
Jowo f'arabale ko gb'emi olorun l'aye ko
M'okan at'eti re kuro ninu etan to kun'nu aye
Gbogbo ohun to ma n dan ko ni wura,
Joo ma fi ididi w'ola, ola aa to ni wa,
Fitila ona re o ni ku lailai, aye re a ma dara si.
Owo o ni wan n'ile wa
Owo Olorun nbe lara wa
Owo Oluwa nba wa lo
Imole a ma tan si
Ope ti mo nda l'ojojumo ree ore okan t'eledua fun mi maa gbo
Modupe mo yin'le f'olu to gbe mi pade alaanu
Mosope mi o kuta l'oju oja ife, eleda lo ba mi se
Alabarin t'eledua yan fun o gangan ni moje
Alabase t'olorun fifun mi gangan ni iwo je
Ajose wa a maa mayo wa o nfun wa l'ayo,
Ka sa maa sora se Ajose wa a maa mayo wa, ka sa maa sora se
Oba ni a lowo a bi'mo
Oba ni a s'owo a j'ere
Oba ni a r'aje jeun
Imole aa ma tan si
Ife okan mi ree, ore okan mi tipetipe maa gbo
Pe ka je imole, imole wa ko tan f'araye ri
Ka f'ara wa lowo, ka jo rin f'olu, ka nipa rere f'ayo
Eni waye lai mu'fe orun se, asan bansa
Aa r'owo lo, aa f'ola we, ka s'ise taa ran wa wa pa bi fun
Ajose wa a maa mayo wa o nfun wa l'ayo, ka sa maa sora se
Ajose wa a maa mayo wa, ka sa maa sora se.
Ajose wa a maa mayo wa…
Ka sa maa sora se…

Comment below with your feedback and thoughts on this post.