Gospel Music Nigerian Gospel Songs Tope Alabi – Oluwa O Tobi (Mp3 + Lyrics)

Tope Alabi – Oluwa O Tobi (Mp3 + Lyrics)

Download Oluwa O Tobi MP3 by Tope Alabi

The prolific Nigerian praise worship gospel singer and songstress who has won lots of great award in the Christian music industry “Tope Alabi” comes through with a powerful tune, as it always comes in the Yoruba dialect. This song is titled “Oluwa O Tobi“.


Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed always…

DOWNLOAD MP3 HERE

Video: Oluwa O Tobi by Tope Alabi

Oluwa O Tobi Lyrics by Tope Alabi

Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
O tobi o, Oluwa giga lorile ede gbogbo
Gbigbega ni O, Iwo lo logo ni orun
Pupopupo ni O, O koja omi okun at’osa, O ga po
Ajulo O o se julo
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
Oba lori aye, O tobi o eh
Agba’ni loko eru, Olominira to n de’ni lorun
O fi titobi gba mi lowo ogun t’apa obi mi o ka
Olugbeja mi to ba mi r’ogun lai mu mi lo t’o segun
Akoni ni O o
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
B’O ti tobi to oo, laanu Re tobi
B’O ti tobi se o, ododo Re tobi o
O tobi tife tife, Oni majemu ti kii ye
Aro nla to gbo jije mimu aye gbogbo alai le tan
Ogbon to koja ori aye gbogbo ooo
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
Akoko O tobi, O tobi o
Oluwa
Ipilese ogborin o yeye
O tobi
Ibere Eni to f’ogbon da ohun gbogbo
Oluwa
Igbeyin ola nla, o la la oo
O tobi
Opin aye a’torun ko si ‘ru Re
Oluwa
O tobi, O o se s’akawe lailai o
O tobi
Agbaagba merinlelogun nki O, O tobi
Oluwa
Awon angeli won n ki O, O tobi
O tobi
Olorun Elijah Ireti Ajanaku
Oluwa
O ma tobi laye mi, O tobi ooo
O tobi
Iwo lo gb’orin t’O o ga, t’O gun, t’O tun fe
Oluwa
O ga, O gun, O fe, O jin, O tobi la la
O tobi

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here