Gospel Music Nigerian Gospel Songs Tope Alabi โ€“ Oluwa O Tobi (Mp3 + Lyrics)

Tope Alabi โ€“ Oluwa O Tobi (Mp3 + Lyrics)

Download Oluwa O Tobi MP3 by Tope Alabi

The prolific Nigerian praise worship gospel singer and songstress who has won lots of great award in the Christian music industry โ€œTope Alabiโ€ comes through with a powerful tune, as it always comes in the Yoruba dialect. This song is titled โ€œOluwa O Tobiโ€œ.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed alwaysโ€ฆ

DOWNLOAD MP3 HERE

Video: Oluwa O Tobi by Tope Alabi

https://www.youtube.com/watch?v=z-fSR1JpXvk

Oluwa O Tobi Lyrics by Tope Alabi

Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko sโ€™eni tโ€™a le fi sโ€™afiwe Re o, O tobi
Ko sโ€™eda tโ€™a le fi sโ€™akawe Re o, O tobi
Oluwa
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko sโ€™eni tโ€™a le fi sโ€™afiwe Re o, O tobi
Ko sโ€™eda tโ€™a le fi sโ€™akawe Re o, O tobi
Oluwa
O tobi o, Oluwa giga lorile ede gbogbo
Gbigbega ni O, Iwo lo logo ni orun
Pupopupo ni O, O koja omi okun atโ€™osa, O ga po
Ajulo O o se julo
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko sโ€™eni tโ€™a le fi sโ€™afiwe Re o, O tobi
Ko sโ€™eda tโ€™a le fi sโ€™akawe Re o, O tobi
Oluwa
Oba lori aye, O tobi o eh
Agbaโ€™ni loko eru, Olominira to n deโ€™ni lorun
O fi titobi gba mi lowo ogun tโ€™apa obi mi o ka
Olugbeja mi to ba mi rโ€™ogun lai mu mi lo tโ€™o segun
Akoni ni O o
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko sโ€™eni tโ€™a le fi sโ€™afiwe Re o, O tobi
Ko sโ€™eda tโ€™a le fi sโ€™akawe Re o, O tobi
Oluwa
Bโ€™O ti tobi to oo, laanu Re tobi
Bโ€™O ti tobi se o, ododo Re tobi o
O tobi tife tife, Oni majemu ti kii ye
Aro nla to gbo jije mimu aye gbogbo alai le tan
Ogbon to koja ori aye gbogbo ooo
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko sโ€™eni tโ€™a le fi sโ€™afiwe Re o, O tobi
Ko sโ€™eda tโ€™a le fi sโ€™akawe Re o, O tobi
Oluwa
Akoko O tobi, O tobi o
Oluwa
Ipilese ogborin o yeye
O tobi
Ibere Eni to fโ€™ogbon da ohun gbogbo
Oluwa
Igbeyin ola nla, o la la oo
O tobi
Opin aye aโ€™torun ko si โ€˜ru Re
Oluwa
O tobi, O o se sโ€™akawe lailai o
O tobi
Agbaagba merinlelogun nki O, O tobi
Oluwa
Awon angeli won n ki O, O tobi
O tobi
Olorun Elijah Ireti Ajanaku
Oluwa
O ma tobi laye mi, O tobi ooo
O tobi
Iwo lo gbโ€™orin tโ€™O o ga, tโ€™O gun, tโ€™O tun fe
Oluwa
O ga, O gun, O fe, O jin, O tobi la la
O tobi

Comment below with your feedback and thoughts on this post.