Gospel Music Nigerian Gospel Songs Tope Alabi – Olorun Ni Yio Ma Je (Mp3 + Lyrics)

Tope Alabi – Olorun Ni Yio Ma Je (Mp3 + Lyrics)

Download Olorun Ni Yio Ma Je MP3 by

The prolific Nigerian praise worship gospel singer and songstress who has won lots of great award in the Christian music industry “Tope Alabi” comes through with a powerful tune, as it always comes in the Yoruba dialect. This song is titled “Olorun Ni Yio Ma Je“.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed always…

DOWNLOAD MP3 HERE

Olorun Ni Yio Ma Je Lyrics by

Olorun ni yio ma je

Olorun ni yio ma je
Olorun ni yio ma je
Lana loni lola o, titi de ayeraye
Olorun ni yio ma jeOlorun ni yio ma je (Olorun ni yio ma je)
Olorun ni yio ma je (titi lai, titi lai, titi lai, titi lai)
Lana loni lola o (Lana o),
Titi de ayeraye (Loni o)
Olorun ni yio ma je (Titi Aye… Titi Aye)Alagbara ni ko se segun o
Ipa nla ni ko de le ku ooo
Aileyipada to la ye ni ikawo
Emi se’ba oluda orun o
(Emi se’ba oluda orun)Olorun ni yio ma je (akoko nda olu nda aye)
Olorun ni yio ma je (patapata pira ogo nibi to pari si)
Lana loni lola o (patapata ola)
Titi de ayeraye
Olorun ni yio majeAiletuwa o ti wa ko to da orun
Tale ri ni ati titi loni
Eni ni igba ti o ni bere
Beni ko lopin
Mo juba akoda aye o
(Patapata ogo)Olorun ni yio maje
(Eni lade to ti dade ka to d’aye)
Olorun ni yio ma je
(Eni lade to ti dade ka to da orun)
Lana loni lola o (Isaju Aye)
Titi de ayeraye (Isaju Orun)
Olorun ni yio ma jeKo seni to da nigba toti njoba o
A o towo eda kan hun ade ori e
Akobi orun o
Olusa ju aiye de
Jehova emi se ba o (okankan oju awon agba lorun)Olorun ni yio ma je (iriju oju awon angeli ojojumo)
Olorun ni yio ma je (iba eni ta won t’orun se ti won o dake)
Kosi ariyan jiyan lori gun merin orun ati aye
Ko ni sai je olorun mo
EeeehOlorun ni yio ma je (iwo ni kan lo ma je olorun titi)
Olorun ni yio ma je (oti je olorun ko to da orun rara)
Ko si ariyan jiyan lori gun merin orun ati aye o
Ko ni sai je olorun mo (Iba o iba o)Olorun ni yio ma je (emi seba oro kodo asiri aye)
Olorun ni yio ma je(asiri aye pelu orun, owo re ni kan lowa)
Lana loni lola o, titi de ayeraye
Olorun ni yio ma je (akoko ati eyin)Translate to English

Drop some comment below about what you think about this post!