Gospel Music Nigerian Gospel Songs Tope Alabi – Eyin Oluwa Halleluyah

Tope Alabi – Eyin Oluwa Halleluyah

Download Eyin Oluwa Halleluyah MP3 by Tope Alabi

The renowned Nigerian praise worship gospel singer and songstress who has won lots of great award in the Christian music industry “Tope Alabi” comes through with a powerful tune, as it always comes in the Yoruba dialect. This song is titled “Eyin Oluwa Halleluyah“ from her 2020 released HYMNAL album.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed always…

DOWNLOAD HERE

Lyrics: Eyin Oluwa Halleluyah by Tope Alabi

Verse 1
Eje ka f;ope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipa a re po o e
Bela nu re duro o lailai

Chorus:
Eyin o Oluwa o Halleluyah
Egbe e ga o o o o o Halleluyah
Eyin Oluwa o Halleluyah
O n logaju o o o o Halleluyah

Verse 2
Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti kerubu sarafu korin si o
Oun re ru awon omi okun

Verse 3
Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori dodo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo

Verse 4
Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo

Share Your Thoughts below