Top Christian Songs The Gratitude – Keresimesi

The Gratitude – Keresimesi

The Gratitude Keresimesi

Download Keresimesi Mp3 by

Here’s another powerful music tune from the COZA Team “The Gratitude“, as this one is titled “Keresimesi”.

Get Audio Mp3, Stream, Share and be blessed.

DOWNLOAD HERE

Lyrics: Keresimesi by Gratitude COZA

(Verse1)
Enukenu to ba n dupe ki ma ma Igbe rara (Any grateful mouth must not be dry)
Apere ti o ba n bo ara ile re ko ma gbodo jo (The basket that feeds his home must not lack)
Iyanu nla ni ife ti jesu ni si wa (this is a wonderful love that have for us)
Omo tuntun jojolo, ose (New born baby, thank you
To wa ra wa pada ni keresimesi yi (Who has come to redeem us all this Christmas)

RELATED POST:  The Gratitude (COZA) – Nothing Is Too Hard for You

(Chorus)
Keresimesi de (Christmas is here)
Keresimesi de (Christmas is here)
Odun ti a bi olugbala araye (The celebration of the day the savior is born)
Keresismesi de odun alayo (Christmas is here a celebration of Joy)
Ko san gbogbo wa sire loruko Jesu (May it bring joy to us all in name)

RELATED POST:  Gratitude COZA - Moving Forward (Mp3 + Lyrics)

(Verse 2)
Awon orun n soro nigba ibi jesu olugbala o (the heavens declare the birth of the savior)
Je ki aye ki o ho iho ayo si oluwa (let the whole earth make a joyful noise unto the Lord)
Nitori a bi olugbala fun wa loni o (Because the savior is born today)
E je k’ayo (Let’s all rejoice)

RELATED POST:  IJO - Gratitude (COZA)

(Vamp)
E yo (Rejoice)
Keresimesi de (Christmas is here)

Share Your Thoughts below