Download Adura Ololufe MP3 by Sola Allyson
Here an amazing song from the Nigerian soul, folk and gospel singer, and song-writer, who came into limelight with the hit album Eji Owuro. Sola Allyson-Obaniyi who is popularly known as Shola Allyson comes through with this song titled โAdura Ololufeโ.
Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed alwaysโฆ
Adura Ololufe Lyrics by Sola Allyson
Adura mogba fun e ololufe mi
Ire ni mo n su fun e ayanfe oko mi ore mi
Oo ni kagbako lโaye oo ni rโogun akoba
Oo ni sโirin lโaye be oo ni tโoju ile mole
Ainifโokanbale o ni yโodo re lailailailailai
Oo ni mโosi lโaye, aye re a ma dara si
Ife eledumare ree e ooo ore mi
O fewa fun re, o fewa fโayo taa ba barawa sโotito
Angeli alayo mi faramo tire nse ni won njo sโise
Iranse alaanu re wa pelu tโemi nwon njo rin po ni
Ibaase โwo layo pupo latagbala eledumare wa inu oluwa aa dun si
Ibaaseโ wo layo pupo latagbala
Eledumare wa o, inu oluwa aa dun si wa
Oba ni a lowo a biโmo
Oba ni a sโowo a jโere
Oba ni a rโaje jeun
Imole aa ma tan si
Imoran mi ree fun e ooo oloro mi
Imoran ni mo n gba e ninu ife to jin oloro mi maa gbo
Pe ko maa sโora se, ore mi atโorun sโora se
Jowo fโarabale ko gbโemi olorun lโaye ko
Mโokan atโeti re kuro ninu etan to kunโnu aye
Gbogbo ohun to ma n dan ko ni wura,
Joo ma fi ididi wโola, ola aa to ni wa,
Fitila ona re o ni ku lailai, aye re a ma dara si.
Owo o ni wan nโile wa
Owo Olorun nbe lara wa
Owo Oluwa nba wa lo
Imole a ma tan si
Ope ti mo nda lโojojumo ree ore okan tโeledua fun mi maa gbo
Modupe mo yinโle fโolu to gbe mi pade alaanu
Mosope mi o kuta lโoju oja ife, eleda lo ba mi se
Alabarin tโeledua yan fun o gangan ni moje
Alabase tโolorun fifun mi gangan ni iwo je
Ajose wa a maa mayo wa o nfun wa lโayo,
Ka sa maa sora se Ajose wa a maa mayo wa, ka sa maa sora se
Oba ni a lowo a biโmo
Oba ni a sโowo a jโere
Oba ni a rโaje jeun
Imole aa ma tan si
Ife okan mi ree, ore okan mi tipetipe maa gbo
Pe ka je imole, imole wa ko tan fโaraye ri
Ka fโara wa lowo, ka jo rin fโolu, ka nipa rere fโayo
Eni waye lai muโfe orun se, asan bansa
Aa rโowo lo, aa fโola we, ka sโise taa ran wa wa pa bi fun
Ajose wa a maa mayo wa o nfun wa lโayo, ka sa maa sora se
Ajose wa a maa mayo wa, ka sa maa sora se.
Ajose wa a maa mayo waโฆ
Ka sa maa sora seโฆ