Download Ojo Nla (Tungba) Mp3 by Bisimanuel
Here’s a song by the African prolific music artist and talented singer “Bisimanuel“. This song is titled “Ojo Nla (Tungba)”, as it was released alongside its video. You’ll also be blessed.
Download Audio Mp3, Stream, Share, and stay graced
Download More BISIMANUEL Songs Here
Lyrics: Ojo Nla (Tungba) by Bisimanuel
1. Ojo nla l’ ojo ti mo yan
Olugbala l’ Olorun mi;
Oye ki okan mi ma yo,
K’o si ro ihin na ka ‘le.
Ojo nla l’ ojo na!
Ti Jesu we ese mi nu
O ko mi ki nma gbadura
Ki nma sora ki nsi ma yo
Ojo nla l’ ojo na!
Ti Jesu we ese mi nu.
2. Tis done, the great transaction’s done!
I am my Lord’s and He is mine:
He drew me and I followed on,
Charmed to confess the voice divine.
3. Mo ti b’ Oluwa sadehun!
Mo di Tire, On di temi,
On l’o pe mi, ti mo si je,
Mo f’ ayo jipe mimo na.