Home Top Christian Songs

Sola Allyson – Imole

Sola Allyson Imole

Download Imole MP3 by Sola Allyson

Here an amazing song from the Nigerian soul, folk and gospel singer, and song-writer, who came into limelight with the hit album Eji Owuro.ย Sola Allyson-Obaniyiย who is popularlyย knownย as Shola Allyson comes through with this song titled โ€œImoleโ€œ.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed alwaysโ€ฆ

DOWNLOAD MP3 HERE

แนขแปŒLร ALLYSON - รŒMแปŒฬLแบธฬ€ (VERSION II)

Lyrics: Imole by Sola Allyson

Jesu
Imole
Ategun ati afara sibi imole
Jesu
Enitโ€™O wa
Ife e Baba
Sโ€™eni tโ€™o fe dโ€™omo

Listen on your favorite platform

Repeat

Imole, latโ€™inu imole
O wa lati da wa pada sโ€™ona imole
Ooun tโ€™o gbโ€™aye
Ko je kโ€™on mo imole
Won diโ€™te moo ife e baba
Olorun ninu eniyan
Eniyan ninu Olorun
Ilekun awon aguntan sinu ile aanu
Ipase eniti mo gba igbala
Nโ€™aye tii fi funni ko
Imole sโ€™ookun aye e mi
Olusewosan emi i mi

Jesu
Imole
Ategun ati afara sibi imole
Jesu
Enitโ€™O wa
Ife e Baba
Sโ€™eni tโ€™o fe dโ€™omo

Eni nwa imole
Won ri ii imole
Won o mo mole
Won diโ€™te imole
Irora yen po gan
Eje atโ€™omi nsan gan
Sibe o n sโ€™agbawi fun wa
Pe baba dariji won
Won o moโ€™ohun a nse
Baba dariji wa o nitori imole
Ninu irora re o tun fi iyonu mu ole re para
O ni iya wo omo re, omo wo iya re
O kigbe lโ€™ohun rara
Olorun mieese tโ€™o o ko mii le
Eese tโ€™o o ju mii le
Eese tโ€™o o yin mi nu
Ongbe po gan, oti kikan lโ€™aye fun un
Awon tโ€™o nwa imole o, won fโ€™iya je imole
O ba pari, o pari
Imole fโ€™emi e sโ€™owo o baba
O pari!

Nitori imole, nitori imole
Aso ipele ya o
Nitori imole
A le pe baba ni baba nitori imole
Isa oku dโ€™ofo
Eni ba fe le wa dโ€™omo

Jesu, oga ogo, olori ogun orun
Omo alade alaafia
Alase orun, aye e baba
Baba lโ€™aaye o, Baba lโ€™aye
Aye e mi tire ni
Tn imole nipase mi
Ogo o mi kโ€™o fogo fun o
Ola a mi kโ€™o bu ola fun o

๐ŸŽต Are you a gospel artist? Get your song featured on CeeNaijaReach millions of gospel music lovers

Promote

Jesu, iwo ni imole
Ategun ati afara sibi imole
Jesu enitโ€™owa
Mo juโ€™ba re, enitโ€™oso mi dโ€™omo

๐Ÿ”’ All songs and media on this page are shared for gospel promotion purposes only. All rights belong to the respective artists and labels. If you are the rights holder and wish content removed, please read our DMCA & Copyright Policy or submit a takedown request here.

Comment below with your feedback and thoughts on this post.