Top Christian Songs Tim Godfrey – Oriki

Tim Godfrey – Oriki

Tim Godfrey Oriki

Download Oriki MP3 by Tim Godfrey

Prolific, multitalented award-winning gospel minister & singer,ย Tim Godfreyย has released a powerful kingdom tune as this one is titled “Oriki“.

Download Mp3, Listen, share and stay blessed.

DOWNLOAD HERE

Lyrics: Oriki by Tim Godfrey

Kaabiesi Atoperi Eledumare mi se
Kaabiesi Agba nla Atoperi Eledumare mi se
Baba mi Awimayehun
Baba mi Awilese o
Baba mi Aleselewi
Baba mi Baba nla ti ngbani
GbaniGbani lโ€™ojo isoro
Eleti gbโ€™ohun gbaroye
Afetilukara bi ajere
Erujeje lโ€™eti okun pupa
Oba to tele bi eni nteni
O ta sanma bi eni taso

Gbongbo Idile Jesse ti ko lee ku lai
Eyin lโ€™Oba to nse oun gbogbo lโ€™odu lodu
Eyin lโ€™Akoda
Eyin lโ€™Aseda
Eyin lโ€™Aweda
Eyin lโ€™Ameda
Ogbagba tirin gbagba
Alagbada ina
Alawotele oorun
Alade gbedegbede bi eni n layin
Edumare moti mope mi wa fโ€™eni tโ€™ope ye fun
Moti fiyin feni tiyin se tiRe oo

Eni to n se mimo
To n je mimo
To n mu mimo
To n gbe bi mimo
To niwa mimo
Alade ogo
Talโ€™aba fi O we
Na You be ana
Na You be oni
Na You tu ni lโ€™ola
Ope ye O o Baba
Edumare gbope wa

Tire ni o
Tire ni o
Mo fi sile fun O
Tire ni o
Tire ni o
Mo fi sile fun O

Owuro mi, osan mi, ale mi o o
Tire ni Oluwa

Tire ni o
Tire ni o
Tire ni o
Tire ni o
Tire ni o
Tire ni o

My praise
My praise
Belongs to You
Belongs to You
My praise
My praise
Belongs to You
Belongs to You
Ese
Ese
Adupe o
Adupe o
Igwe
Igwe
Igwe
Igwe
Igwe
Igwe
Igwe
Igwe

Comment below with your feedback and thoughts on this post.