Download IYIN MP3 by Sola Allyson
Here an amazing song from the Nigerian soul, folk and gospel singer, and song-writer, who came into limelight with the hit album Eji Owuro. Sola Allyson-Obaniyi who is popularly known as Shola Allyson comes through with this song titled โIYINโ.
Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed alwaysโฆ
Video: IYIN by Sola Allyson
IYIN Lyrics by Sola Allyson
Eni ba mo โnu ro, lo le mo ope da
Eni ba ni arojinle a saa ma dupe
Emi mo โnu ro, mo ya a wa dupe
Olorun ti a ko le da duro, mo gbe O ga o
Olorun ti a ko le mu lowo dani
Mo gbe O ga o
Too ba loya ta lole da O duro, eto inu Re lo wa, eto owo Re lowa
Mo gbe O ga o
Olorun ti a ko le da duro, mo gbe O ga o
Kabiyesi, Kabiyesi Re, Baba Agba
Kabiyesi, Kabiyesi Re, Oba awon oba
Kabiyesi, Kabiyesi Re, Baba Agba
Kabiyesi, Kabiyesi Re, Oba awon oba
Kabiyesi Re o, Baba Agba
Oba to joko lori ite o, maa sola Re lo Oluwa
Kabiyesi, Kabiyesi Re, Baba Agba
Kabiyesi, Kabiyesi Re, Oba awon oba
O fi imole sโaso bora
Oba to fโimole sโaso bora
Ori obiri aye lo joko si, imole lo fi sโaso bora
Oba to fโimole sโaso bora
O fi imole sโaso bora
Kabiyesi Re Oluwa
Emi mi n bu ola fun O nigba gbogbo Oba mi
Ni gbogbo aye ko seni to da bi Re, Oluwa
Iwo to n joko sinu awon orun, Oluwa
O fi imole sโaso bora
Oluwa mo gbe O ga o
Awon orun n ba mi yin O o, pe O se
Oluwa mo gbe O ga o
Awon orun n ba mi yin O o, pe O se
Oluwa mo gbe O ga o
Gbogbo ise Re n ba mi yin O o, pe O se
Mo da ohun mi po mo gbogbo ise Re, mo so bee, O seun
Oluwa mo gbe O ga o
Awon orun n ba mi yin O o, pe O se
A yin O, Oba mimo
A yin O, Oloore wa
A yin O, Olugbala
Iwo lo n sโagbara wa
A yin O, Oba mimo
A yin O, Oloore wa
A yin O, Olugbala
Iwo lo n sโagbara wa
A yin O o, Oba mimo
Ebo ope wa ree o
Latโogbun okan wa wa ni
Wa gba a Oluwa Olorun
A yin O, Oba mimo
A yin O, Oloore wa
A yin O, Olugbala
Iwo lo n sโagbara wa
Iwo ni mo wa gbe ga
Iwo ni mo wa fโiyin fun
Olorun mi to n gbe nibi giga
Iwo ni mo wa gbe ga
Iwo ni mo wa gbe ga
Iwo ni mo wa fโiyin fun
Olorun mi to n gbe nibi giga
Iwo ni mo wa gbe ga
Iwo ni mo wa gbe ga o
Oba to rโojo aanu sโori iseda mi, Oluwa
Olorun mi to n gbe nibi giga
Iwo ni mo wa gbe ga
Iwo ni mo wa gbe ga
Iwo ni mo wa fโiyin fun
Olorun mi to n gbe nibi giga
Iwo ni mo wa gbe ga
Alpha, Omega
Iwo ni mo fโiyin fun o, Baba
Alpha, Omega
Iwo ni mo fโiyin fun o, Baba
Oba to mo ibere, iwo ni Alpha,
Oba to mo opin, Iwo ni Omega
Iwo ni mo fโiyin fun o, Baba
Iyin Re o ni tan lenu mi titi aye mi, Oluwa
Alpha Omega
Iwo ni mo fโiyin fun o, Baba
Oloore ofe, Eleruniyin
Olorun Agbaye o, mo gbe O ga
Oloore ofe, Eleruniyin
Olorun Agbaye, mo gbe O ga
Oloore ofe, Eleruniyin
Unexplainable, Indescribable, Unsearchable, Incredible
Mo gbe O ga
Oloore ofe, Eleruniyin
Olorun Agbaye, mo gbe O ga
Iyin ye Olorun wa, Oba to n gbo adura
Iyin ye O o, Olorun wa
Oba to n fi aanu gbadua
Bi o ba se โWo too wa leyin mi, nibo lemi o ba wa, mi i ba ti bโaye lo
Oba to n gbo adura
Iyin ye Olorun wa, Oba to n gbo adura
O ti n sโise Re bo, Iwo yoo se lasepe o
O ti n sโise Re bo, Iwo yoo se lasepe
O ti n sโise Re bo laye wa, Iwo yoo se lasepe
O ti n fโaanu gba mi bo Oluwa,
Iwo yoo gba mi tan o, Agbanilagbatan ni O o
O ti n fโaanu yo mi bo o, Oba to mu mi deโbi, Iwo yo se lasepe
O ti n sโise Re bo, Iwo yoo se lasepe
O ti n sโise Re bo laye wa, Iwo yoo se lasepe
Gbโadura mi goke, Baba, gbโadura mi goke
Oba Afesejin
Gbโadura mi goke