Download Logan Ti Ode MP3 by Tope Alabi
The prolific Nigerian praise worship gospel singer and songstress who has won lots of great award in the Christian music industry โTope Alabiโ comes through with a powerful tune, as it always comes in the Yoruba dialect. This song is titled โAnLogan Ti Odegeliโ.
Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed alwaysโฆ
Video: Logan Ti Ode by Tope Alabi
Logan Ti Ode Lyrics by Tope Alabi
Emi moโun ojumi tiri
Mo moโun etimi ti gbo
Mo moโun ojumi tiri
Mo moโun etimi ti gbo
Logan to gbo iro ayo re o
Mo moโun aye ma tiwi
Mo moโun eniyan ma tiso
Won ti pe wa ni agan ri
Bo ya won ti pe o loโloshi ri
Sugbon logan to de o
Olugbala lโaye mi leto
Sugbon logan to de yi o
Olugbala lโaye e leto
Aye to ti daru tele tele oo
Logan ti o de
Oro ti eniyan ti n fi alufani re
Logan ti o de
Oro ti ko dara ti a ti so si o
Logan ti o de
Oruko ti kin se ti e ta ti pe o
Logan ti o de
Ani logan ti o de o
Olugbala, aye e leto
Logan ti o de o
Olugbala, aye e leto
Logan ti jesu de
Olugbala, lโaye e leto
Ko si oruko ti aye o le peni
Won a ma peni lโagan lona gbogbo
Bo ba lowo lโowo, agan ni
Bo ba bimo o, agan ni
Bo ba tโegbe ko dโagba, agan loje
Sugbon logan ti o de
Sope logan ti o deโฆ