
Download Isin MP3 by Sola Allyson
Here an amazing song from the Nigerian soul, folk and gospel singer, and song-writer, who came into limelight with the hit album Eji Owuro. Sola Allyson-Obaniyi who is popularly known as Shola Allyson comes through with this song titled โIsinโ.
Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed alwaysโฆ
Download More SOLA ALLYSON Songs Here
Lyrics: Isin by Sola Allyson
A fโope fโOlorun
Lโokan ati lโohun wa
Eni sโohun โyanu
Nโnu Eni tโaraye n yo
Gbatโa wa lโomโowo
On na lโo ntoju wa
O si fโebun ife
Se โtoju wa sibe
Oba Onibuore
Ma fi wa sile laelae
Ayo ti ko lโopin
On โbukun yโo je ti wa
Pa wa mo ninu oore
To wa, gbโa ba damu
Yo wa ninu ibi
Lโaye ati lโorun
Kโa fโiyin on ope
FโOlorun, Baba, Omo
Ati Emi mimo
Ti o ga julo lorun
Olorun kan laelae
Tโaye atโorun n bo
Bee lo wa di isiyi
Beeni yo wa laelae
Eyo ninu Oluwa, e yo
Eyin tโokan re se dede
Eyin tโo ti yan Oluwa
Le โbanuje atโaro lo
E yo! E yo!
E yo ninu Oluwa, e yo!
E yo! E yo!
E yo ninu Oluwa, e yo!
E yo torโ On lโOluwa
Lโaye ati lโorun pelu
Oro Re borโ ohun gbogbo
O lโagbara lati gbala
E yo! E yo!
E yo ninu Oluwa, e yo!
E yo! E yo
E yo ninu Oluwa, e yo!
โGbatโ a ba n ja ija rere
Ti ota fere bori wa
Ogun Olorun tโa ko ri
Po ju awon ota wa lo
E yo! E yo!
E yo ninu Oluwa, e yo!
E yo! E yo
E yo ninu Oluwa, e yo!
Okan mi n yo ninu Oluwa
โTori O je iye fun mi
Ohun Re dun pupo lati gbo
Adun ni lati rโoju Re
Emi n yo ninu Re
Emi n yo ninu Re
Gba gbogbo lo n fi ayo kun okan mi
โTori emi n yo ninu Re
O ti n wa mi pe ki n to mo O
โGbati mo rin jina sโagbo
O gbe mi wa sile lโapa Re
Nibi ti papa tutu wa
Emi n yo ninu Re
Emi n yo ninu Re
Gba gbogbo lo n fi ayo kun okan mi
โTori emi nyo ninu Re
Oore atโanu Re yi mi ka
Orโofe Re n san bi odo
Emi Re n to, o si n se โtunu
O mba mi lo si โbikibi
Emi n yo ninu Re
Emi n yo ninu Re
Gba gbogbo lo n fi ayo kun okan mi
โTori emi nyo ninu Re
Iwo to fe wa la o ma sin titi
Oluwa Oloore wa
Iwo to nso wa ninu โdanwo aye
Mimo logo Ola Re
Baba, Iwo lโa o ma sin
Baba, Iwo lโa o ma bo
Iwo to fe wa lโa o ma sin titi
Mimo lโogo ola Re
Iwo to fโagan lโomo to n pe ranse
Ninu ola Re to ga
Eni tโo ti sโalaileso si n dupe
Fun โse ogo ola Re
Baba, Iwo lโa o ma sin
Baba, Iwo lโa o ma bo
Iwo to fe wa lโa o ma sin titi
Mimo lโogo ola Re
Eni tโebi n pa le ri ayo ninu
Agbara nla Re to ga o
Awon to ti n woju Re fun aanu
Won tun n yo ninu ise Re
Baba, Iwo lโa o ma sin
Baba, Iwo lโa o ma bo
Iwo to fe wa lโa o ma sin titi
Mimo lโogo ola Re
Baba E se aanu Yin duro
Baba E se o
Baba E se o, aanu Yin duro
Baba E se aanu Yin duro
Baba E se
Baba E se o
Baba E se, aanu Yin duro
Eyin ni o, Olorun o
Eledumare, Oba ogo
Eyin ni o, Olorun
Awimayehun, Alagbara
Eyin ni o, Olorun o
Eledumare, Oga ogo
Eyin ni o, Olorun o
Awimayehun, Alagbara
Kโa to da aye, nโIwo ti wa
Kโole mi to so ninu iya mi, lโO ti n joba
Olorun Baba o, Olorun omo
Olorun Emi mimo
Iwo nโibere ohun gbogbo
Iwo ni opin ohun gbogbo
Awimayehun, Alagbara
Eyin ni o, Olorun o
Eledumare, Oga ogo
Eyin ni o, Olorun o
Awimayehun, Alagbara
Oluwa orun on aye
โWo nโiyin atโope ye fun
Bawo la ba ti fe O to!
Onibu ore
Orun ti n ran, atโ afefe
Gbogbo eweko n so โfe Re
โWo lโO n mu irugbin dara
Onibu ore
Onibu ore
Bawo la ba ti fe O to!
Onibu ore
Fun ara lile wa gbogbo
Fun gbogbo ibukun aye
Awa yin O, a si dupe
Onibu ore
Fun idariji ese wa
Ati fun ireti orun
Ki lโohun tโa ba fifun O
Onibu ore
Onibu ore
Bawo la ba ti fe O to!
Onibu ore
O se mi laanu, ma a polongo Re
Oba tโo se mi laanu, eh eh, ah ah
Ma a polongo Re
O se mi laanu, ma a polongo Re
Oba tโo se mi laanu, eh eh, ah ah
Ma a polongo Re
Oju mi ti ri, eti mi ti gbo
Enu mi ma soro nโpa ise Oluwa
Oju mi ti ri o, eti mi ti gbo
Enu mi ma soro nโpa ise Oluwa
Oju mi ti ri, eti mi ti gbo
Enu mi ma soro nโpa ise Oluwa
Oju mi ti ri, eti mi ti gbo
Enu mi ma soro nโpa ise Oluwa
Olori ijo tโorun
Lโayo lโa wole fun O
KโO to de, ijo tโaye
Yโo ma korin bi tโorun
A gbe okan wa sโoke
Ni โreti tโo ni โbukun
Awa kigbe, awa fโiyin
FโOlorun igbala wa
Bi a wa ninu โponju
Tโa n koja ninu ina
Orin ife lโawa yo ko
Ti yo mu wa sun mo O
Awa n sape, a si yo
Ninu ojurere Re
Ife tโo so wa di Tire
Yโo pa wa mo titi lae
Iwo mu awon eeyan Re
Koja isan idanwo
A kโ yo beru wahala
Tori O wa nitosi
Aye, ese, atโEsu
Koju โja si wa lasan
Lโagbara Re, a o segun
A o si ko orin Mose
Aribiti, Arabata
Eyin lโatobiju
Aribiti, Arabata
Eyin lโatobiju
Oluwa
Oluwa, Eyin lโatobiju
Aribiti, Arabata
Eyin lโatobiju
Aribiti, Arabata
Eyin lโatobiju
Oluwa
Latโojo ti mo ti n rin
Eh oh, eh eh eh eh oh
Emi o ri โru Olorun eyi ri
Eh oh, eh oh
Latโojo ti mo ti n rin
Eh oh, eh oh
Emi o ri โru Olorun eyi ri
Eh oh, eh oh
Ojo nla lโojo ti mo yan
Olugbala lโOlorun mi
O ye ki okan mi ma yo
Kโo si ro ihin na kale
Ojo nla lโojo na
Ti Jesu we ese mi nu
O ko mi ki n ma gbadura
Ki n ma sora, ki n si ma yo
Ojo nla lโojo na
Ti Jesu we ese mi nu
Ise igbala pari na
Emi di tโOluwa mi loni ati lojo gbogbo
Ohun lโo pe mi, ti mo si je o
Mo fโayo jโipe mimo na
Ojo nla lโojo na
Ti Jesu we ese mi nu
O ko mi ki n ma gbadura
Ki n ma sora, ki n si ma yo
Ojo nla lโojo na
Ti Jesu we ese mi nu
Eyin orun gbo eje mi,
Eje mi ni ojojumo
Emi yโo ma so dotun titi
Iku yo fi mu mi rele
Ojo nla lโojo na
Ti Jesu we ese mi nu
O ko mi ki n ma gbadura
Ki n ma sora, ki n si ma yo
Ojo nla lโojo na
Ti Jesu we ese mi nu
Gbese ope mi po, emi o le san tan
Amo o sibesibe, ma a se โwon ti mo le se
Baba Alaanu mi, E ma se o Baba
Gbese ope mi po, emi o le san tan
Amo o sibesibe, ma a se โwon ti mo le se
Baba Alaanu mi, E ma se o Baba
Mo n tesiwaju lโona na
Mo n goke sii lojojumo
Mo n gbadura bi mo ti n lo
Oluwa jo gbe mi soke
Oluwa, jo gbe mi soke
Fa mi lo si ibi giga
Apata tโo ga ju mi lo
Oluwa jo gbe mi soke
Ife okan mi ko duro
Laarin โyemeji atโeru
Awon miran le ma gbe be
Ibi giga lโokan mi n fe
Oluwa, jo gbe mi soke
Fa mi lo si ibi giga
Apata tโo ga ju mi lo
Oluwa jo gbe mi soke
Mo fe de โbi giga julo
Ninu ogo didan julo
Mo n gbadura ki n le de be
Oluwa mu mi de โle na
Oluwa, jo gbe mi soke
Fa mi lo si ibi giga
Apata tโo ga ju mi lo
Oluwa jo gbe mi soke
Igbagbo mi duro lโori
Eje atโ ododo Jesu
N ko je gbekele ohun kan
Leyin oruko nla Jesu
Mo duro le Kristi Apata
Ile miran, iyanrin ni
Mo duro le Kristi Apata
Ile miran, iyanrin ni
Bโire-ije mi tile gun
Ore-ofe Re ko yi pada
Bโo ti wu ki iji na le to
Idakoro mi ko niye
Mo duro le Kristi Apata
Ile miran, iyanrin ni
Mo duro le Kristi Apata
Ile miran, iyanrin ni
Ore-ofe, ohun
Adun ni lโeti wa
Gbohun-gbohun re yโo gba orun kan
Aye yโo gbo pelu
Ore-Ofe sa
Nโigbekele mi
Jesu ku fun araye
O ku fun mi pelu
Ore-Ofe to mi
Sโona alaafia
O n toju mi lโojojumo
Ni irin ajo mi
Ore-Ofe sa
Nโigbekele mi
Jesu ku fun araye
O ku fun mi pelu
Je kโ ore-ofe yi
Fโagbara fokan mi
Ki n le fi gbogbo ipa mi
Atโ ojo mi fun O
Ore-Ofe sa
Nโigbekele mi
Jesu ku fun araye
O ku fun mi pelu
Ninu irin ajo mi, beeni mo n korin
Mo n toka si Kalfari, nibi eje na
Idanwo lode ninu, lโota gbe dide
Jesu lโO nto mi lo, isegun daju
A! mo fe ri Jesu, ki n ma wโ oju Re
Ki n ma korin titi, nipa oore Re
Ni ilu ogo ni, ki n gbohun soke
Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi
Ninu ise isin mi, bโokunkun ba su
Un o tubo sunmo Jesu, yโO tan imole
Esu le gbโ ogun ti mi ki nle sa pada
Jesu lโo nto mi lo, ko sโewu fun mi
A! mo fe ri Jesu, ki n ma wโ oju Re
Ki n ma korin titi, nipa oore Re
Ni ilu ogo ni, ki n gbohun soke
Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi
Bi mo tile bo sinu afonifoji
Imole itoni Re yโo mole si mi
Yโo na owo Re si mi, yโO gbe mi soke
Un o tesiwaju bโO ti n to mi lo
Nigbati iji aye yi ba yi lu mi
Mo ni abo tโo daju labe apa Re
YโO ma fโowo Re to mi titi de opin
Ore ododo ni, A! mo ti fโE to
A! mo fe ri Jesu, ki n ma wโ oju Re
Ki n ma korin titi, nipa oore Re
Ni ilu ogo ni ki n gbohun soke
Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi
Nipa ife Olugbala
Ki yโo si nkan
Oju rere Re ki pada
Ki yโo si nkan
Owon lโeje tโo wo wa san
Pipe lโedidi orโofe
Agbara lโowo tโo n gba ni
Ko le si nkan
Bi a wa ninu iponju
Ki yโo si nkan
Igbala kikun ni tiwa
Ki yโo si nkan
Igbekele Olorun dun
Gbigbe ninu Kristi lโere
Emi si n so wa di mimo
Ko le si nkan
Ojo ola yio dara
Ki yโo si nkan
โGbagbo le korin ni โponju
Ki yโo si nkan
A gbekele โfe Baba wa
Jesu n fun wa lโohun gbogbo
Ni yiye tabi ni kiku
Ko le si nkan
Amin.